ADEBOYE KI AARE KU ORIIRE, GANI ADAMS GBARA YILE NI SOOSI
Pastor Adeboye kii ku oriire
Oludari Agba fun Redeemed Christian Church of God, Pastor E. A. Adeboye, ti ki Aaare Ona Kakanfo Gani Adams ku oriire lori bi o se de ipo naa.
Ninu atejade kan, Adeboye ni ohun ti ko je ki oun wa ni Oyo nibi ti won ti se ayeye oye naa nip e oun lati lo sibi etomiiran kan ni.
O wa so pe Aare ni atileyin oun.
Bakan naa, Aare tuntun se bebe nigba to lo dobale gbalaja, to yika otun, yika osi, to si gbara yile fun Olorun ni soosi ni ilu Eko.
Comments