Posts

Showing posts from 2017

ÌJỌBA TÍ KÒ SÍ LỌ́WỌ́ ÀWỌN ỌBA NI KÒ JẸ́ KÍ AYÉ Ó GÚN RÉGÉ MỌ́ – OLUWO

Image
Oluwo ti ilu Iwo, Oba Abdul-Rasheed Adewale ni ohun ti ko je ki aye roju mo ko jina lati wa kiri. O ni ijoba ti ko si lowo awon Oba mo lo faa. O ni Oba nikan lo n ba Eledumare je oruko po ti awon wa je eni to wa laarin awon ara ilu ati Eledua. O ni awon ni Eledua fi gbogbo akoso ile aye le lowo, nitori pe Oba ni oko oso, oko aje ati oko elebo-loogun. Ti eku ko ba ke bi eku mo, ti eye ko ke bi eye mo tabi omo eniyan ti ko fohun bi omo eniyan. Oba nikan lo mo ohun ti a n se. Oba nikan lo mo bi a se n be awon alale ti gbogbo nnkan si maa bere si ni tuba-tuse. Oluwo pe akiyesi si asiko ti o je pe Oba lo n dari gbogbo nnkan ni ilu, o ni eyi to ba fe ru won loju, won mo bi won se n fi ese ile too, sugbon ti ko ri bee mo ni aye ode oni. Oluwo ni peluu bi o se ri yii naa, a ko gbodo kawo gbera, a ni lati kun won lowo naa ni nitori pe “Aafaa to ni iyan yoo mu, omo tire naa ko ni je tira”.

MO MAA N SA FUN AWON OBINRIN TO BA FE BA MI SE ISEKUSE – AKIN LEWIS

Image
Agba osere Akin Lewis, ti so pe opo obinrin lo maa n konu si oun pe ki won jo ni ibalopo. O ni ti o ba je pe gbogbo obinrin to ti konu si oun pe ki won jo ni asepo ni oun ba gba fun ni, boya un kiba ti ku bayii. O so fun awon oniroyin pe oun ti oun maa n se nip e oun maa n sa danu ti obinrin kan ba ti denu ibasun ko oun. O ni iyawo oun ni olubadamoron ati ore timotimo oun, to si je pe un kii maa be sita mo bi oun se maa n se tele.

OSUPA ATI PASUMA GBE IJA WONU ODUN TUNTUN

Image
Adura alaafia ati irepo ti awon eniyan kan gba fun agbo fuji gba die, sugbon adura naa ko gba tan o. Ni odun to n pari yii, ija to wa laarin awon ogbologbo onifuji meji, Saheed Osupa ati Wasiu labi Pasuma, tun je jade. Koda, ija naa ko pari rara. Ija naa jeyo ni nnkan bii ose meji seyin, nigba ti ayeye ojo ibi alaadota odun Pasuma waye. Opo osere lo lo ba Pasuma se ajoyo, ti won si sere funun.  Lara won ni King Sunny de ati Wasiu yinde K1 de Ultimate. Sugbon Osupa ati Malaika ko lo sibe. Eyi tumo sip e won ti gbe ija naa wo inu odun tuntun.

IDI TI MO FI SO OMO MI NI FEMI ADEBAYO – OGA BELLO

Image
Osere pataki, Alagba Adebayo Salami, ti so asiri bi o se so omo bibi inu re ti oun naa je elere fiimu, Femi Adebayo, ni oruko to n je di oni olonii. O so ninu iforowanilenuwo kan pe oun so o ni Femi lati fi se ayesi fun baba-nigbejo oun kan ni, ti eni naa je Alagba Femi Okunnu. Loya pataki ni baba naa je ni Eko, to si ti se opo ejo nla-nla ni aseyori. Oga Bello ni ise loya lo wu oun lati se tele. O ni aisi owo ni ko je ki oun lo kawe gboye lori re. O ni oun sise gege bii akowe ni oofisi Alagba Femi Okunnu nigba kan, ti baba naa si je baba-igbejo, iyen godfather fun oun di oni olonii. Oga Bello wa salaye pe nigba ti oun bi Femi, ti oun fe so o loruko, oun wa pinnu pe oruko ti baba-nigbejo oun n je naa ni oun yoo fun un. Oga Bello ni ninu gbogbo fiimu ti oun ti se, ASEWO TO RE MEECCA lo gbayi ju, to fun oun lowo ju, to si tubo so oun di ilumo-o-kaa.

5TH YEAR REMEMBRANCE OF GLORIOUS EXIT OF A RARE GEM "BISI KOMOLAFE".

Image
It may look like remembrance of unbearable pain in the minds of her families, friends and fans but there is nothing we can do about it. As I, CyberProf-Alabi Samuel-Johnson NoWay ForOpposition promised all of us in this forum that I wouldn't be reluctant to keep us updated concerning past and present issues happening in the ancient city of Ibadan, Oyo State and Nigeria at large, I am hereby reminding us concerning the death of our beloved Ibadan actress who died in 2012. GLOOM enveloped Ibadan, the Oyo State capital, going to 5 years as the body of popular Yoruba actress, Bisi Komolafe, was buried. Family members, friends, admirers and other sympathizers sobbed uncontrollably as people gathered to bid farewell to the talented actress.  The mass, which held at St. Mary’s Catholic Church, Oke- Padre, Ibadan, was conducted by Rev. Father Benedict Ugwoegbu. Rev. Fr. Benedict Ugwoegbu, in his sermon said: “Death is no respecter of anybody. Everybody’s turn will come; do not

“MY HEART IS FILLED WITH SADNESS” – PASUMA WONDER CONDOLES WASIU AYINDE OVER DAUGHTER'S DEATH

Image
Fuji Singer, Alabi Pasuma a.k.a Pasuma Wonder has reached out to King Wasiu Ayinde a.k.a Kwam 1 over his daughter’s death, in the early hours of Tuesday, in Canada from diabetic complications. According to Pasuma Wonder, 34-year-old Wasilat Anifowese’s death has filled his heart with sadness. Pasuma said that “speechless @kingwasiuayindemarshal, Words cannot express how deeply sorry I am to hear about Wasilat, My deepest sympathy for your loss. My thoughts and prayers are with you and your entire family.  May your beautiful memories sustain and bring comfort to you during this difficult season. My heart is filled with sadness. Please accept our deepest sympathies and know that my prayers are with you during this time Sir.”

INÚ ẸGBẸ́ ÒSÈLÚ APC NÁÀ NI MO SÌ WÀ – SARAKI

Image
Aare ile igbimo asofin agba, Omowe Bukola Saraki ati olori ile igbimo asoju, Alagba Dogara pelu awon oloselu to loruko ninu egbe oselu APC ni won lo sabewo si Alagba Uche Secondus to jawe olubori gege bi alaga gbo-gbo-gbo fun egbe oselu PDP. Abewo yii wa je ki awon kan maa gbee kiri pe Saraki ati awon kan to loruko ninu egbe oselu APC fe pada sinu egbe oselu PDP. Saraki ni ko si ohun to joo lowo bayii. O ni bi ilu se maa toro, ti awon ti ko n’ise maa r’ise, ti owon gogo gbogbo nnkan maa wale ni o koko je oun logun bayii, kii se kikuro ninu egbe kan bo si omiran.

WIFE OF PRESIDENT, AISHA BUHARI SPOTTED IN “KEKE NAPEP

Image
A photo of Aisha, wife of President Muhammadu Buhari, inside the tricycle better known as ‘Keke NAPEP’, is trending on social media. She sat comfortably in the passengers’ corner and posed for photographs. It’s not clear when the picture was taken but there are unconfirmed reports that it was during her visit to Katsina to inaugurate children and maternity clinic at the General Hospital, Daura, hometown of her husband

WASIU AYINDE CRIES OVER HIS DEAD DAUGHTER

Image
Popular fuji musician, Alhaji Wasiu Ayinde , has paid tribute to her daughter , Wasilat Olaronke Ashabi Ayinde , who passed on in Canada on Tuesday. Wasilat was said to have died after an undisclosed illness . Many people have since been expressing condolences to the musician otherwise called K 1 de Ultimate over the incident . Ayinde , however, broke his silence on Thursday in a tribute he wrote to the daughter , describing her as a gift from God . The musician wrote, “ My Olaronke Ashabi: 17 th, July , 1983 to 12 th , December 2017. These are two dates in history that shall never be forgotten ever in my life . The first , a date you came to this world , and the latter , the day you departed. I give glory and thanks to God Almighty who gave you to me for a purpose . I have seen that several times , that I am privileged to have been your father and also for you to the kind of a child that also doubled as my friend . “ About your sickness, all our efforts, through med

CELEBRITIES STORM FUJI MUSIC STAR, MALAIKA 200 MILLION NAIRA LEKKI HOUSE

Image
Fuji music star, Alhaji Sulaimon Alao Adekunle popularly known as Malaika is enjoying the euphoria of his 200 million naira Lekki house warming ceremony that took place on Sunday 10th December 2017 at Salvation Avenue, Kajola, Ibeju Lekki, Lagos. King of Fuji music, Alhaji Wasiu Ayinde ‘K1’, Alhaji Saheed Osupa, Alhaji Abass Akande Obesere, Alhaji Sefiu Alao, Alhaji Kollinton Ayinla with other colleagues were role calls. Islamic Scholars that attended the event were Sheik Muyindeen Ajani Bello, Sheik Surajudeen Asuquna, Sheik Yusuf Abolore Okutadidi . And Islamic singers were Alhaja Rukayat Gawat, Alhaji Sauti Arewa and Alhaja Kafayat Singer, Alhaja Mistura Success. Global Excellence publisher, Mayor Akinpelu, and City People publisher, Seye Kehinde, Kunle Raheed, Charles Nwagbara, Tade Asifat also attended the memorable event with other well-wishers.

KWAM 1 SPEAKS ON DAUGHTER'S DEATH

Image
The popular Fuji musician, Wasiu Ayinde Marshal, also known as Kwam 1, has confirmed the death of one of his daughters, Wasilat. Wasilat died in Canada after a brief illness. The deceased, said to be 34 years old, reportedly died in the early hours of Tuesday from complications arising from diabetes. On Thursday, Kwam 1 extolled the virtues of his late daughter while saying he accepts her death as the will of Allah. He wrote: “17th July 1983 -12th December 2017, The two dates in history and shall never be forgotten ever in my life. The first, a date you came to this world and the later the day you departed. “I give glory & thanks to God Almighty who gave you to me as a gift by you coming to this world for a purpose and through me. I have seen that severally while you were growing that I am privileged to be your father and also to the kind of a child that also double as my friend. “About your sickness and all our efforts through medical means that was availabl

ỌYỌ STATE INAUGURATES 14-MEMBER PRIMARY HEALTHCARE BOARD

Image
Oyo State governor, Senator Abiola Ajimobi, has charged members of the Oyo State Primary Health Care Board to ensure an efficient and effective healthcare delivery at the state’s primary healthcare centres and health posts. Governor Ajimobi, represented at the inauguration of the board by the state’s Commissioner for health, Dr Azeez Adeduntan, said this would ensure that general hospitals are decongested and work optimally. The governor said that governments all over the world invest in primary healthcare centres to boost access to healthcare, especially for indigent persons, urging them to put in their best to make the agency thrive. Acting Executive Secretary, Oyo State Primary Health Care Board, Dr Lanre Abass, in his presentation on the agency’s journey so far, said the board, among other things, would be expected to help determine the minimum resources required for health clinics, health posts and primary healthcare centres in the state. Noting that Oyo State has 686

AJIMOBI PRESENTS N267bn 'BUDGET OF STABILISATION'

Image
Oyo State Governor Abiola Ajimobi has presented a budget of N267billion to the State House of Assembly for ratification and approval. The presentation of the proposal tagged 'Budget of Stabilisation',  The 2018 budget is N60billion greater than the 2017 budget of N207billion and N94billion higher than the 2016 budget of N173billion. In essence, the government is expecting about N93billion from the Federation Account in 2018 compared to N69billion that was received in 2017. The internally generated revenue for the coming year is projected at N112billion compared to 2017 projection of N107billion, as the increase in revenue is based on cost-effective revenue collection through the passage of relevant laws. Total recurrent is also projected at N213billion while the capital receipts are estimated at N43billion compared to 2017 estimates of N183billion as recurrent and N24billion as capital receipts for 2017. A breakdown of the 2018 budget revealed that recurrent e

OLUBADAN: MOGAJIS ISSUE SEVEN-DAY ULTIMATUM TO 21 IBADAN KINGS

Image
The Ibadan M ogajis (family heads) , under the aegis of Council of Authentic Ibadan Mogajis, have issued a seven -day ultimatum to the 21 kings installed by the Oyo State Governor, Abiola Ajimobi, to withdraw their threat to recommend Olubadan of Ibadan land, Oba Saliu Adetunji , for removal or face the wrath of Ibadan people . The 21 kings , who were on August 27 , 2017 installed by the governor , had on Monday given a 21 -day ultimatum to the monarch to be of good conduct or risk being removed from the throne. At a press conference addressed by the 21 kings at Mapo Hall , Ibadan, the Oyo State capital , leader of the group, Oba Lekan Balogun , who is also the Otun Olubadan of Ibadan land, accused the monarch of taking unilateral decisions on behalf of the ‘Olubadan-Kings-in-Council ’ and inciting the people against the state government. At the end of a meeting held by the Ibadan Mogajis on Thursday , eight of the 21 kings , who are high chiefs in Ibadan , were urged to st

Ibadan indigenes set up Mega City status C’tte

Image
As part of efforts to make Ibadan a mega city by 2040, the Central Council of Ibadan Indigenes (CCII) has inaugurated 20 committees toward the realisation of the project. Ibadan The CCII President-General, Mr Yemi Soladoye, inaugurated the committees in Ibadan on Sunday. CCII, which was founded in 1982, is the umbrella body of all Ibadan indigenous clubs. It has 236 clubs affiliated to it. Soladoye said that the CCII had repositioned to ensure that Ibadan would become a mega city by 2040. He called on Ibadan indigenes to work together to achieve the aim. “We have come up with robust programmes and projects for economics, political and cultural rennaisance of Ibadan land. “There is no room for pessimism, cynism or armchair patriotism. Let nobody discourage us that the project is impossible; in fact we have started already. “We should be tired of still chorusing the greatness of our forefathers almost 150 years after. “We need new songs and heroes in Ibad

Ajimobi, prophet with honour among Oyo Muslims

Image
“A prophet is not without honour, except in his own country, and in his own house,” so say the Scriptures. This was however not the case for the governor of Oyo State, Senator Abiola Ajimobi, who was recently celebrated by the Muslim community of the state in grandeur. The community said it decided to roll out the drums in honour of the governor in acknowledgment of his penchant for promoting religious harmony and for delivering good governance. The Lekan Salami Sports Complex, Adamasingba, venue of the ceremony, witnessed an unprecedented gathering of Islamic faithful, scholars and preachers from Oyo State and across the Southwest zone, under the aegis of Muslim Ummah of South West Nigeria (MUSWEN). At the epochal event, the enviable award of “The Most Equitable Governor in the History of Oyo State” was conferred on Ajimobi for what the Muslim community called his equitable, fair and just relationship with Christians, Muslims and traditionalists across the state. Already, Aji

Accord Party directs Oyo chapter to deregister ex-Governor, Rasidi Ladoja POLITICS

Image
The National Working Committee (NWC) of Accord Party on Tuesday directed its Oyo state chapter to deregister former Governor of the state, Rasidi Adewolu Ladoja. Chairman, South East, National Working Committee of the party, Mr Innocent Igbokwe who issued this directive during an official visit of the NWC members to the party’s secretariat at Aremo in Ibadan described the ex-governor’s exit from the party as a blessing. He declared that his exit would also pave way for progress and true internal democracy in the party. He said “Accord party was established in 2006 while Ladoja joined the party in 2010 to contest the state governorship election in 2011. “Accord is a party, no single person can be powerful than the party. “Accord was not funded or owned by Ladoja, so, his defection to another party is his constitutional right and has no significant effect on the party in Oyo or nationwide. “The national body of the party did not enjoy his stay since he joined. “

200,000 PEOPLE LIVING WITH HIV IN ỌYỌ STATE

Image
Dr Sani Aliyu, Director-General, National Agency for the Control of AIDS (NACA) says an estimated 200,000 people are living with HIV in Oyo State. He made the disclosure on Tuesday in Ibadan during a courtesy call on Gov. Abiola Ajimobi of Oyo State at the executive council chamber of the governor’s office. The delegation was led by Aliyu, included representatives of World Health Organisation, other international donor and funding agencies. Aliyu stated that only 16,000 out of the estimated 200, 000 persons living with HIV in the state are currently on treatment. “We have a gap between the number of infected persons and those on treatment. We have a gap between infected pregnant women and those receiving treatment. “We also have issues with the number of new infections recorded,’’ he said. The NACA boss stated that 10, 000 pregnant women in Oyo State are living with HIV, adding that about 50 people contact HIV in the state on a daily basis. He stated that the state

39 ATTESTED FOR VIOLATING ENVIRONMENTAL LAWS IN ỌYỌ STATE

Image
THE Oyo State Government at the weekend arrested 39 persons for violating the environmental laws and regulations of the state during the National Monthly Environmental Sanitation. The State Commissioner for Environment and Water Resources, Mr Isaac Ishola disclosed this after monitoring the exercise at Custom area, Bodija, Total Garden and Agodi Gate all in Ibadan metropolis. The Commissioner, who was on the monitoring exercise with the Special Adviser to Governor Abiola Ajimobi on Community Relations Mr Murisiku Siyanbade and officials of the Ministry, warned that the government will not tolerate citizens’ negative disposition to environmental sanitation in the state. He urged the general public to stop disobedience to the environmental sanitation exercise in the State, stating that whoever disobeys the observance of the exercise between the stipulated hours would be arraigned before the mobile court for proper sanctions. Mr Ishola appealed to all the residents of the

REDEEMER’S UNIVERSITY EXPELS ACTOR MACARONI ON HIS GRADUATION DAY OVER HIS SOCIAL MEDIA POST

Image
Redeemer’s University have expelled one of their students, actor and entertainer, Debo Adedayo aka Mr Macaroni, just few days before his graduation over a post he made on his Facebook page. According to the university which is owned by the General Overseer of the Redeemed Christian Church of God (RCCG), Pastor Adeboye, Debo’s Facebook post was offensive and portrayed the university in bad light, an act that constitutes serious misconduct and punishable by expulsion. Here’s the school’s letter of expulsion, and the comedian’s reaction below; The post that got Debo expelled He wrote; “This is the reason why I have been expelled from Redeemer’s University after years of passionate service and sacrifice to the University. I didn’t lead a riot as president of the Students Association, I didn’t steal, I didn’t fight, I didn’t break any rules and regulation. “I posted this after a meeting with Prof Wande Abimbola.  The school mgt invited me for an

South-west APC hails governors, ministers, other representatives in region

Image
L-R Former Interim National Chairman of the All Progressives Congress, Chief Bisi Akande; a former Governor of Ogun State, Aremo Segun Osoba; and a former Governor of Osun State, Chief Olagunsoye Oyinlola, during the APC Southwest stakeholders' meeting, held at the Governor's Office, Ibadan... on Thursday. Photo: Oyo State Governor's Office. The leadership of the South-west All Progressives Congress has applauded the performance of governors and National Assembly members elected on the ticket of the party, as well as ministers appointed from the region. The leaders gave the commendation through the former Interim National Chairman of the APC, Bisi Akande, after a stakeholders’ meeting held at the Oyo State Governor’s Office, Ibadan, on Thursday. He said that the meeting assessed the performance of governors, National Assembly members and those appointed into the Federal Executive Council from the region and was satisfied with their stewardship so far. Mr. Akande sa

2019: We are not perturbed with your alliance – Oyo Senator, Adesoji Akanbi tells PDP

Image
The Senator representing Oyo South District, Rilwan Adesoji Akanbi has declared that the ruling All Progressives Congress (APC), was not perturbed by the re-grouping of Peoples Democratic Party (PDP) stalwarts to capture the state in 2019. Akanbi challenged the APC to come together and ensure “the continuity of progressives in power in the state beyond 2019”. Akanbi, however, warned against the infiltration of non – progressive elements into the ruling APC in the state, saying such might jeopardize the desire to produce a progressive governor in 2019. Going down the memory lane, Akanbi noted that some progressives in Oyo state laboured hard and remained consistent to ensure the return of progressives into power after the defeat of former governor of the state, Late Lam Adesina. He said “I am one of those who sustained progressives in Oyo state. I remained in the progressive until we came back to power in 2011. I used my resources, my time and my energy to keep the pr

IKU AKUFA LAARIN AWON ORE DAVIDO: IBANUJE D’ORI OMO BABA OLOWO K’ODO!

Image
Aye n fura pe oogun oloro lo seku pa ore Davido meta Inu ibanuje nla ni Davido wa bayii, latari bi awon ore re bii meta, Tagbo, Chime ati DJ Olu, se iku ojiji tele ara won. Ko pe ti awon ore naa jo se faaji tan ni wahala dede de ba won, ti won si di ero orun ka to seju pe. Awon kan ni oti amuju lo fa wahala naa, ti awon kan si n so pe o seese ko je oogun oloro. Sugbon awon olopaa ni bi o tile je pe awon dokita ti se ayewo ijinle, iyen autopsy, lori iku to pa Tagbo ati Chimey, won ko tii gbe esi re jade. Won so eyi ni ifesi si ohun ti awon kan n so pe ayewo naa fihan pe oti amuju ati oogun oloro lo sokunfa adanu naa. Inu Davido baje lori isele naa debi pe ibi ayeye odun Fela, iyen Felabration, to ye ko ti korin, ko lee lo sere nibe.

OMO WASIU AYINDE PARIWO SITA: ‘OLOLUFE MI FE KI N MAA LO OOGUN OLORO!’

Image
Okan lara awon omo agba onifuji, Wasiu Ayinde, K1 De Ultimate, iyen Farouk Wasiu Ayinde, ti so asiri bi ololufe re kan se fe ti oun si ki oun maa lo oogun oloro bii cocaine, heroine ati awon miiran to gbona janjan. Farouk, ti oun naa je akorin, so pe obinrin naa n so lemolemo pe oun naa gbodo maa ta si oogun oloro, bee oun ko setan lati se bee. O ni ko si ni erongba oun lati maa ta si awon oogun buruku naa.

Zambian Footballer’s Daughter Who Died Same Day He Was Playing Against Nigeria has been buried

Image
Zambian winger, Augustine Mulenga, lost his twin daughter, on Saturday, October 8th, while he was playing against the Super Eagels of Nigeria, in Uyo, Akwa Ibom. Augustine scored a goal, but it was disallowed by the referee. Officials knew the winger lost a daughter but could not tell him because he offered hope in helping his country qualify for the 2018 World Cup in Russia. Mulenga was only told about the sad news after the match. The player is pictured below, being comforted on arrival from Nigeria. The little girl has been buried.

GBENGA DANIEL FE BA BODE GEORGE FORI GBARI LORI ALAGA PDP

Image
Bi egbe PDP se fe mu alaga re tutntun lati ile Yoruba ti fa ki awon olori egbe naa ni Kootu Oojiire maa da ofun tolo lori ipo naa o. Awon akoni to n du ipo naa ti fee to meje, gege bi awon akoni Fagunwa ninu Igbo Irunmole. Lara won to koko dide lati du ipo naa ni Oloye Bode George.  Bakan naa ni Alagba Jimi Agbaje, Ojogbon Tunde Adenuran ati Alhaji Taoheed Adedoja. Sugbon lowolowo yii, Otunba Gbenga Daniel lo jo pe o n mile titi, to si ti n kaakiri Naijiria lati baa won agbaagba egbe dunaa-dura.

PAGA! ODO GBE AGUNBANIRO MEJI LO!

Image
Ibanuje tun ti sele ni ile awon agunbaniro meji kan, ti oruko won n je Oguntola Wasiu Babatunde ati Danjuma Salihu, tori odo ti gbe awon mejeeji lo. Ni ileto kan ti won n pe ni Assakio ni Lafia, ni Ipinle Nasarawa, ni isele laabi naa gbe se. Asosu ajo NYSC ni agbegbe naa, Hajiya Zainab Isah, so pe ojo Sunday ti awon odomokunrin naa lo we lodo ni odo gbe won lo. O ni, “Nnkan buruku ni isele naa, sugbon mo gbagbo pe Olorun yoo te won safefe rere.” O wa wa ro awon agunbaniro to ku ki won maa sora se ni gbogbo ibi ti won ba wa.

I DON'T PLAN TO DEPOSE OLUBADAN ---- AJIMOBI TELLS BUHARI

Image
Oyo State Governor Abiola Ajimobi yesterday said he would not depose Olubadan of Ibadan, Oba Saliu Adetunji. Ripples over installation of new kings has prompted Ibadan youths to call on President Muhammadu Buhari to prevail on the governor not to make any pronouncement that could further puncture the peace in the city. Addressing State House correspondents yesterday after a meeting with President Buhari, the governor said the issue had been hijacked by politicians. He said: “I assured him that come rain, come shine, I will never depose the Olubadan because he is a father; and a son does not depose his father. Even though he has done so many things that could be used to remove him, I will never remove him. We have to continue to show respect. “I also made him to realise that, that particular chieftaincy declaration is being politicised; politicians have hijacked it. Of 11 council members, two of them are dead, and we have nine remaining. It is only one who is not suppor

EDE AIYEDE MAA N WAYE LAARIN EMI ATI IYAWO MI – MIKE BAMILOYE

Image
Gbajugbaja oni fiimu ti emi, Mike Bamiloye,  ti se alaye pe ede aiyede maa n waye laarin oun ati aya re, Gloria Bamidele leekokan. Bi awon mejeeji se jo maa n se, paapaa niu fiimu, opo eniyan lo ro pe won kii jaa leekookan ni. Sugbon nigba ti Mike Bamiloye n soro lori bi won se jo wa po fun odun mokandinlogbon gege bi loko-laya, o ni awon dupe lowo Olorun pe o fi oyin ati adun si igbeyawo awon, pelu awon omo to yan to yanju. O ni aya rere ni Olorun fun oun, ti iyaafin naa, Gloria Bamiloye si so pe igbeyawo awon larinrin gidi ni. Sugbon Mike Bamiloye ni leekookan, ede aiyede maa n wa ninu ile ati nigba ti awon ba n seto fiimu. O ni bi eyi ba sewon a pe ara awon, awon a si soro nipa re, ti yoo si tan lokan kaluku awon.

IDI TI MO FI N SE BUSINESS ADMINISTRATION NI UNILAG – ODUNLADE ADEKOLA

Image
Laipe yii ni awon ololufe osere fiimu pataki, iyen Odunlade Adekola, yoo ba a je iresi, nigba ti o ba fe se ayeye ikekoo-jade ni University of Lagos. Eko Business Administration, ti awon omo ile iwe maa n pe ni Bus Admin, ni o n se nibe, to si je pe odun karun-un , 500 Level lo wa. O so fun awon oniroyin pe oun ti ni Diploma tele ni Moshood Abiola Polytechnic ni Abeokuta. O ni idi ti oun fi yan Business Admin laayo ni pe o je ilana eko kan too wulo fun gbogbo eniyan. O ni bi eniyan lowo, o gbodo mo ona lati de e mole; bi eniyan nile ise, o gbodo ni imo Business Admin, to fi mo dokita to wa ni osibitu.