OSUPA ATI PASUMA GBE IJA WONU ODUN TUNTUN
Adura alaafia ati irepo ti awon eniyan kan gba fun agbo fuji gba die, sugbon adura naa ko gba tan o. Ni odun to n pari yii, ija to wa laarin awon ogbologbo onifuji meji, Saheed Osupa ati Wasiu labi Pasuma, tun je jade. Koda, ija naa ko pari rara.
Ija naa jeyo ni nnkan bii ose meji seyin, nigba ti ayeye ojo ibi alaadota odun Pasuma waye.
Opo osere lo lo ba Pasuma se ajoyo, ti won si sere funun.
Lara won ni King Sunny de ati Wasiu yinde K1 de Ultimate. Sugbon Osupa ati Malaika ko lo sibe. Eyi tumo sip e won ti gbe ija naa wo inu odun tuntun.
Comments