MO MAA N SA FUN AWON OBINRIN TO BA FE BA MI SE ISEKUSE – AKIN LEWIS
Agba osere Akin Lewis, ti so pe opo obinrin lo maa n konu si oun pe ki won jo ni ibalopo.
O ni ti o ba je pe gbogbo obinrin to ti konu si oun pe ki won jo ni asepo ni oun ba gba fun ni, boya un kiba ti ku bayii.
O so fun awon oniroyin pe oun ti oun maa n se nip e oun maa n sa danu ti obinrin kan ba ti denu ibasun ko oun.
O ni iyawo oun ni olubadamoron ati ore timotimo oun, to si je pe un kii maa be sita mo bi oun se maa n se tele.
Comments