RARA O, EMI KI MO BI IBEJI O! TAIWO ARAMOKUN PARIWO
Onifiimu Taiwo Aramokun ti so pe oun ko tii bi ibeji miiran o, leyin eyi ti Olorun yonda fun oun ni nnkan bii odun die seyin.
Opo eniyan lo ti bere sii ki I ku ewu ibeji lanti-lanti lati ojo meji seyin, nigba to gbe foto awon omo tuntun kan jade.
Eyi lo mu u se alaye pe molebi oun kan lo bi awon omo naa, kii se oun.
Ti a ko ba gbagbe, Taiwo ati baale re ni ede aiyede ni aipe yii.
Comments